Àwọn Agbègbè Òkèrè Brítánì
From Wikipedia, the free encyclopedia
Àwọn Agbegbe Okere Britani (British Overseas Territories) ni awon agbegbe merinla okere Britani, ti won kii se ara Britani gangan.[1] Won je iseku Ile Obaluaye Britani ti won ko i ti gba ominira tabi dibo lati duro gege bi agbegbe Britani.