Ilẹ̀ Yorùbá
From Wikipedia, the free encyclopedia
Ilẹ̀ Yorùbá ni agbègbè ìgbéró àsà ilẹ̀ àwọn ọmọ Yorùbá ní Ìwọ̀òrùn Áfríkà. Ilẹ̀ Yorùbá fẹ̀ láti Nàìjíríà, Benin títídé Togo, agbègbè ilẹ̀ Yorùbá fẹ̀ tó 142,114 km2 106,016 km2 inú rẹ̀ (74.6%) bọ́sí Nàìjíríà, 18.9% bósí orílẹ̀-èdè Benin, àti 6.5% yìókù bósí orílẹ̀-èdè Togo. Ilẹ̀ ìgbéró àsà Yorùbá yìí ní iye àwọn ènìyàn bíi mílíọ́nù 55.[1][2]
Quick Facts Ilẹ̀ YorùbáIlẹ̀ Yorùbá Southwest Nigeria, Western Nigeria, South and Central Benin, Central Togo and Ghana, Apá ilẹ̀ ...
Ilẹ̀ Yorùbá Ilẹ̀ Yorùbá Southwest Nigeria, Western Nigeria, South and Central Benin, Central Togo and Ghana | |
---|---|
Cultural region | |
Nickname(s): Ilẹ̀ Káarò-Õjíire | |
Ibùdó ilẹ̀ Yorubaland (green) ní West Africa (white) | |
Apá ilẹ̀ | Benin Nàìjíríà Togo |
- Ibi ìtẹ̀dó ilẹ̀ Ifẹ̀ | 400 BCE |
- Oyo Empire | 1400 |
- British Colony | 1862 |
- French Colony | 1872 |
- Dahomey (Now Benin) | 1904 |
- Nigeria | 1914 |
Founded by | PYIG (Proto Yoruba-Itsekiri-Igala) |
Regional capital | • Ilẹ̀-Ifẹ̀ (Cultural/Spiritual) • Ibadan (Political) • Lagos/Eko (Economic) |
Former seat | • Oyo-Ile (Old Political) |
Composed of | |
Government | |
• Type | Monarchies • Oba (King) • Ògbóni (Legislature) • Olóye (Chiefs) • Balógun (Generalissimo) • Baálẹ̀ (Village/Regional heads in Western Yorubaland) • Ọlọja (Village/Regional heads in Eastern Yorubaland) |
Area | |
• Total | 142,114 km2 (54,871 sq mi) |
Highest elevation | 1,055 m (3,461 ft) |
Lowest elevation | −0.2 m (−0.7 ft) |
Population (2015 estimate) | |
• Total | ~ 55 million |
• Density | 387/km2 (1,000/sq mi) |
In Nigeria, Benin and Togo | |
Demographics | |
• Language | Yoruba |
• Religion | Christianity, Islam, Yoruba religion |
Time zone | WAT (Nigeria, Benin), GMT (Togo) |
Close