Jẹ́mánì Nazi ati Raik Keta ni awon oruko to wopo fun orile-ede Jemani labe ijoba Adolf Hitler ati Egbe Osise Sosialisti Apapo Jemani (NSDAP), lati 1933 de 1945. Raik Keta (Third Reich) () tokasi ijoba Nazi gege bi atele si Ile Obaluaye Romu Mimoigba ailaju ni Europe (962–1806) ati si Ile Obaluaye Jemaniodeoni (1871–1918). Jemani Nazi ni oruko onibise meji, the Deutsches Reich (Raik Jemani), lati 1933 de 1943, nigba to di Großdeutsches Reich (Raik Jemani Titobiju).
First stanza of ["Das Lied der Deutschen"]error: {{lang}}: text has italic markup (help) followed by ["Horst-Wessel-Lied"]error: {{lang}}: text has italic markup (help)