Joycelyn Elders
Olóṣèlú / From Wikipedia, the free encyclopedia
Minnie Joycelyn Elders (abiso Minnie Lee Jones; August 13, 1933) je is an American oniwosan omode ati alakoso eto ilera igboro. O je ogagun igbakeji adari ni ile-ise awon omose alafunse ise ilera igboro ati omo Afrika Amerika akoko to je yiyan sipo gege bi Oniwosan Agba Orile-ede Amerika, o fi ipo yi sile ni 1994. Lowolowo Elders je ojogbon eniowo ninu eko iwosan omode ni Yunifasiti Arkansas fun Sayensi Oniwosan.
Quick Facts 15th Surgeon General of the United States, Ààrẹ ...
Joycelyn Elders | |
---|---|
15th Surgeon General of the United States | |
In office September 8, 1993 – December 31, 1994 | |
Ààrẹ | Bill Clinton |
Asíwájú | Robert A. Whitney (acting) |
Arọ́pò | Audrey F. Manley (acting) |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Minnie Lee Jones 13 Oṣù Kẹjọ 1933 (1933-08-13) (ọmọ ọdún 90) Schaal, Arkansas, U.S. |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Democratic |
Military service | |
Branch/service | Public Health Service Commissioned Corps, United States Public Health Service |
Years of service | USA: 1953–1956 |
Rank | USPHS: Vice Admiral |
Close
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |