Ẹnu
From Wikipedia, the free encyclopedia
. Nínú ìmọ̀ ẹ̀yà ara ènìyàn, ẹnu ni ẹ̀yà ara àkọ́kọ́ tí ó kángun sí ona ọ̀fun tí ohun jíjẹ àti ohun mímu ń gbà kọjá, tí ó sì pèsè itọ́ fún ìrọ̀rùn ahọ́n kí ọ̀rọ̀ ó lè já geere. [1] Gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà ara ìfọ̀, ẹnu ní agbára lati pèsè àti láti gba itọ́ dúró pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ epithelium tí ó wà nínú ẹnu. Lára iṣẹ́ rẹ̀, láti ẹnu ni iṣẹ́ dídà óúnjẹ ti bẹ̀rẹ̀. Bẹ́ẹ̀, ó tún ń ṣiṣẹ́ ìfọ̀, ọ̀rọ̀ sísọ tàbí ìbánisọ̀rọ̀
Quick Facts Details, Latin ...
Ẹnu | |
---|---|
Head and neck | |
Photo outside the human mouth | |
Details | |
Latin | os, cavitas oralis |
Anatomical terminology |
Close
Nígbà tí àkọ́ṣe iṣẹ́ ohùn ń ti inú tááná ahọ́n , ètè àti àrùgbọ̀n nílò orísirísi ohùn àti ọ̀rọ̀.