Kóstá Rikà
From Wikipedia, the free encyclopedia
Kóstá Rikà (pípè /ˌkoʊstə ˈrikə/ ( listen)), lonibise o je Orile-ede Olominira ile Kosta Rika(Spánì: [Costa Rica] error: {{lang}}: text has italic markup (help) tabi República de Costa Rica, pronounced [reˈpuβlika ðe ˈkosta ˈrika]) je orile-ede ni Arin Amerika, o ni bode mo Nicaragua ni Ariwa, Panama ni ilaorun ati guusu, mo Okun Pasifik ni iwoorun ati guusu ati mo Omi-okun Karibeani ni ilaorun.
Orile-ede Olominira ile Kosta Rika Republic of Costa Rica [República de Costa Rica] error: {{lang}}: text has italic markup (help)
| |
---|---|
Motto: "[Vivan siempre el trabajo y la paz] error: {{lang}}: text has italic markup (help)" (Spanish) "Long live work and peace" | |
Orin ìyìn: [Noble patria, tu hermosa bandera] error: {{lang}}: text has italic markup (help) (Spanish) Noble homeland, your beautiful flag 1 | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | San José |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Spani |
Lílò regional languages | Mekatelyu, Bribri |
Orúkọ aráàlú | Kóstá Rikà |
Ìjọba | Oseluarailu onilana-igbepapo (Orile-ede Olominira Oniaare) |
• Ààrẹ | Rodrigo Chaves Robles |
• Igbákejì Ààrẹ 1k | Stephan Brunner |
• Igbákejì Ààrẹ 2k | Mary Munive |
Aṣòfin | Iléìgbìmọ̀ Aṣòfin |
Ilominira Filole | |
• latowo Spein | September 15, 1821 |
• latowo Meksiko | October 4, 1824 |
• latowo UPCA | March 21, 1847 |
• Recognized by Spain | May 10, 1850 |
Ìtóbi | |
• Total | 51,100 km2 (19,700 sq mi) (128th) |
• Omi (%) | 0.7 |
Alábùgbé | |
• July 2009 estimate | 4,253,897[1] (123rd) |
• Ìdìmọ́ra | 85/km2 (220.1/sq mi) (107th) |
GDP (PPP) | 2009 estimate |
• Total | $48.881 billion[2] |
• Per capita | $10,579[2] |
GDP (nominal) | 2009 estimate |
• Total | $29.318 billion[2] |
• Per capita | $6,345[2] |
Gini (2007) | 48.0[1] Error: Invalid Gini value · 30th |
HDI (2007) | ▲ 0.854 Error: Invalid HDI value · 54th |
Owóníná | Costa Rican colón (CRC) |
Ibi àkókò | UTC-6 (CTZ) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | otun |
Àmì tẹlifóònù | +506 |
Internet TLD | .cr |
Kosta Rika, to tumosi "Eti Odo Olora", ti pa constitutionally ise ologun re re pelu ilana-ibagbepo ni 1949.[3][4][5] Ohun nikan ni orile-ede Amerika Latini to wa ni akojo awon orile-ede 22 oseluarailu pipejulo.[6] Kosta Rika lemolemo ti wa larin awon orile-ede Amerika Latini to gaju nipa Atoka Idagbasoke Eniyan, o si wa ni ipo 54th lagbaye ni odun 2007.[7] O wa ni ipo keta lagbaye, ati akoko ni gbogbo Amerika, nipa Atoka Bi Ayika Se Wa ni 2010.[8]
Ni 2007 ijoba Kosta Rikan sekede eto fun Kosta Rika lati di orile-ede ti ko lo karbon ni 2021.[9][10][11] Gege bi New Economics Foundation se so, Kosta Rika gba ipo kinni ninu Atoka Planeti Adunnu beesi ni o je orile-ede "alawoewe julo" lagbaye.[12]