Ìbàdàn
olúìlú ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní Nàìjíríà / From Wikipedia, the free encyclopedia
Ìbàdàn jẹ́ olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ìlú Ìbàdàn ni ìlú tí ó tóbí jùlọ ní apá ìwọ̀òrùn Afríkà, bẹ́ẹ̀ sì ni ó jẹ́ olú ìlú ìjọba fún ìpínlè Ọ̀yọ́. Ìbàdàn jẹ́ ilú àwon jagunjagun tí wọ́n dá sílẹ̀ lẹ́yìn tí ìjọba Ọ̀yọ́ Kàtúnga túká nígbà tí Àwọn Fúlàní ṣe ìkọlù sí ìjọba Ọ̀yọ́ nígbà náà. Orúkọ tí wọ́n ń pe ilú yí (Ìbàdàn) ní ó túmọ̀ sí ẹ̀bá ọ̀dàn.
Quick Facts Orílẹ̀-èdè, Ìpínlẹ̀ ...
Ìbàdàn | |
---|---|
Fọ́rán àwòrán èdè Ilẹ̀ Ìbàdàn | |
Nickname(s): Ile Oluyole | |
Coordinates: 7°23′47″N 3°55′0″E | |
Orílẹ̀-èdè | Naijiria |
Ìpínlẹ̀ | Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ |
Government | |
• Gomina | Abiola Ajimobi |
• Alaga, Ariwa | Ademola Kamil Omotoso |
• Alaga, Ariwa-Ila Oorun | Olugbenga Ayinde Adewusi |
• Alaga, Ariwa-Iwo Oorun | Aderemi Ayodele |
• Alaga, Guusu-Ila Oorun | Abiodun Bolarinwa Adedoja |
Area | |
• Total | 1,190 sq mi (3,080 km2) |
Population (2005) | |
• Total | 2,550,593 |
• Density | 2,140/sq mi (828/km2) |
• Metro density | 600/sq mi (250/km2) |
• Awon eya eniyan | Yoruba |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
Website | http://www.oyostate.gov.ng/ |
Close