Kókó ọmú
From Wikipedia, the free encyclopedia
Kókó omú tí àwon míràn mò sí orí omú jé ará omú tí o dide sita tí omi omú sì ún gbà jáde. [1] Kókó omú àti agbegbe rè(areola) ma ún dúdú ju ara omú toku lo, bí o tile jé wipe didusi kókó omú lè jé tori oyún(àwon oloye gbagbo pé ìdí èyi nipé kí omo ba le tete rí orí omú nígbà tí o ba fé jeun [2] ), àkókò nkan osu tàbí tori aìsàn. [3] Kókó omú le dide sókè si nígbà otutu tàbí nígbà tí nkan bà kan, o lè jé enu omode nígbà tí fun lomu tàbí iwofokan nigba ibalopo, aìsàn náà tún le fa kí ori omú le [4]