Mira Sorvino
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America / From Wikipedia, the free encyclopedia
Àdàkọ:Use mdy dates Àdàkọ:Use American English
Mira Sorvino | |
---|---|
Sorvino at the 2013 Vienna Opera Ball | |
Ọjọ́ìbí | 28 Oṣù Kẹ̀sán 1967 (1967-09-28) (ọmọ ọdún 56) New York City, New York, U.S. |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Harvard University (AB) |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 1985–present |
Olólùfẹ́ | Christopher Backus (m. 2004) |
Àwọn ọmọ | 4 |
Parent(s) |
|
Àwọn olùbátan | Michael Sorvino (brother), Amanda (sister) |
Mira Katherine Sorvino ( /ˈmiːrə sɔrˈviːnoʊ/; wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdílọ́gbọ̀n oṣù kẹsàn-án, ọdún 1967) jẹ́ Òṣèré Amẹ́ríkà. Ó gba Àwọ́ọ̀dù Akadẹ́mì àti Golden Globe fún Òṣèré tó segi lẹ́yìn ọgbà fún ipa rẹ̀ ní eré Woody Allen tó pẹ̀ ní Mighty Aphrodite (1995).
Orúko rẹ̀ wà lára àwọn orúkọ àkọ́kọ́ tó bẹ̀rẹ̀ àwọn fíìmù bíi my and Michele's High School Reunion (1997), Mimic (1997), Lulu on the Bridge (1998), The Replacement Killers (1998), Summer of Sam (1999), and Like Dandelion Dust (2009). Fún àwọn iṣẹ́ rẹ̀ lórí tẹlẹfísọ̀n, wọ́n yànhọ́ fún àwọn àwọ́ọ̀dù bíi primetime Emmy Award for Outstanding Lead Actress in a Limited Series or Movie fún ipa tó kó gẹ́gẹ́ bí Marilyn Monroe ní Norma Jean & Marilyn (1996), àti wí pé wọ́n yànhọ́ lẹ́ẹ̀mejì fún Golden Globe for Best Actress – Miniseries or Television Film, bákan náà fún ipa tó kó gẹ́gẹ́ bí Marilyn Monroe àti ipa to kó gẹ́gẹ́ bí olórí Òṣèré ní Human Trafficking (2005).