Ìmòye
From Wikipedia, the free encyclopedia
Ìmòye (Philosophia; Philosophy) ni igbeka awon isoro gbogbo ati pipilese lori ohun bi iwalaye, imo, iyi, ironu, emi ati ede.[1][2] O yato si awon ona idojuko ibere pipilese (bi Iseawo, itan-abiso tabi awon iseona) nipa ona oniyewo, ati ni gbogbo ona sistemu ati igbokan le re lori iyan alalaye.[3] "Philosophy" (filosofi) wa lati ede Griki φιλοσοφία (philosophia), to tumo si "ife oye".[4][5][6]