Ilẹ̀ Ọbalúayé Rómù (Roman Empire) tabi Ileo Róòmù ní ìgbà eyin toloselu to sele ni Romu Atijo, tó jẹ́ ti ìjọba apàṣẹ-wàá tó ní àgbègbè káàkiri Europe àti yípo àgbègbè Mediterranean.[6] Oro yi bere si je lilo lati juwe ile ijoba Romu nigba ati leyin obaluaye ibe akoko Augustus.
Quick Facts
Name: Senatus Populusque Romanus (SPQR) ("The Senate and People of Rome") [nb 1] Ilẹ̀ Ọbalúayé Rómù Roman Empire
The maximum extent of Roman Empire under Trajan in AD 117
Capital
Rome was the sole political capital until AD 286 There were several political centres during the Tetrarchy while Rome continued to be the nominal, cultural, and ideological capital. Constantine re-founded and established the city of Constantinople as the new capital of the empire in 330[1]. Mediolanum (Milan) was its western counterpart during the increasingly frequent East/West divisions. The western imperial court was later relocated to Ravenna.