Ìṣeọ̀rọ̀àwùjọ
From Wikipedia, the free encyclopedia
Ìṣeọ̀rọ̀awùjọ ni àgbéwòkà onísáyẹ́nsì àwùjọ.[1] Ó jẹ́ sáyẹ́nsì àwùjọ (a term with which it is sometimes synonymous) tó únlo oríṣi ọ̀nà ìwádìí oníìrírí[2] and critical analysis[3] láti ṣàgbédìde àpapọ̀ ìmọ̀ nípa àgbéṣe àwùjọ ọmọnìyàn. Fún ọ̀pọ̀ àwọn aṣeọ̀rọ̀àwùjọ èrò iṣẹ́ wọn ni láti ṣe ìwadìí tí yíò ṣe é múlò tààrà sí ètòìlú àwùjọ àti ìtọ́jú, nígbàtí àwọn míràn dá ṣẹ́ wọn lórí ìtúnṣe ìlóye aláròjinlẹ̀ àwọn àgbéṣe àwùjọ. Orí-ọ̀rọ̀ ṣegbàjá láti orí-pele oníkékeré ìṣàgbéṣe ẹnìkọ̀kan àti ìbáṣepọ̀ dé orí-pele onígbàngbà àwọn sístẹ́mù àti ìpele àwùjọ.[4]
Àyọkà yìí únfẹ́ ìyílédèdà sí Yorùbá. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ ṣàtúnṣe sí ìyílédèdà |