Albert Lutuli
From Wikipedia, the free encyclopedia
Albert John Lutuli (o tun je kiko bi Luthuli;[1] c. 1898 – 21 July 1967), bakana bi oruko re ni ede Zulu Mvumbi, je oluko ati oloselu ara Guusu Afrika. Lutuli je didiboyan si ipo aare Kongresi Omoorile-ede Afrika (ANC), nigbana bi agbajo ombrela to lewaju ilodi si ijoba akereniye alawofunfun ni Guusu Afrika. O gba Ebun Nobel Alafia ni 1960 fun ipa to ko ninu akitiyan alaije jagidijagan si apartheid. Ohun ni omo Afrika akoko, ati eni akoko ti kii se ara Europe ati ara awon Amerika, to gba Ebun Alafia Nobel.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Quick Facts President of the African National Congress, Asíwájú ...
Albert Lutuli | |
---|---|
Albert Lutuli (~1960) | |
President of the African National Congress | |
In office 1952–1967 | |
Asíwájú | James Moroka |
Arọ́pò | Oliver Tambo |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | c. 1898 Bulawayo, Southern Rhodesia |
Aláìsí | (1967-07-21)Oṣù Keje 21, 1967 Stanger, KwaZulu-Natal, South Africa |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | African National Congress |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Nokukhanya Bhengu |
Close