Alice Brady
From Wikipedia, the free encyclopedia
Alice Brady (Orúkọ Àbísọ rẹ ni Mary Rose Brady; Ọjọ́ ìbí je November 2, 1892 si October 28, 1939) jẹ́ Òṣèré kàn ní orílé èdè Améríkà tí ì bẹrẹ iṣé náà ni àkókò tí wọn ń pé ní Silent Era, èyí tí o padà di àsìkò tí wọn pè ní Sound Film/talkies. O sìse Títí di oṣù mẹ́fà kí ó pàdúnu èmi rẹ sórí ààrùn Jẹjẹrẹ Cancer ní ọdún 1939. Àwọn eré Fíìmù rẹ náà ní; My Man Godfrey ni 1936, nínú rẹ̀ ní ó tí ṣeré gẹgẹ bí Carole Lombardi àti nínú fíìmù "In Old Chicago ní ọdún 1937 èyí tí ì gbà àmi w Akádẹ́mì Fún Best Supporting Actress. Ni ọdún 1960, àwọn orúkọ fún àmì ẹ̀yẹ Hollywood Walk of Fame Motion pictures, èyí tí orúkọ rẹ̀ náà wà lára wọn fún àwọn ohùn tí o tí ṣe àfikún nínú iṣẹ eré ṣíṣe. Àmì ẹ̀yẹ tí o gbà wá ni 6301 Hollywood Boulevard.[2] O jẹ́ òṣèré tó gba Amì Ẹ̀yẹ Akádẹ́mì bí Obìnrin Òṣeré Kejì tí ó Dídárajùlọ.
Alice Brady | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Mary Rose Brady (1892-11-02)Oṣù Kọkànlá 2, 1892 New York City, U.S. |
Aláìsí | October 28, 1939(1939-10-28) (ọmọ ọdún 46) New York City, U.S. |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 1914–1939 |
Olólùfẹ́ | James L. Crane (m.1919–div.1922) |
Àwọn ọmọ | 1[1] |
Parent(s) |
|