Babajide Sanwo-Olu
Olóṣèlú / From Wikipedia, the free encyclopedia
Babájídé Olúṣọlá Sanwó-Olú (ojoibi ) jẹ́ olóṣèlú àti Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó to wà lórí àléfà lọ́wọ́́lọ́wọ́. Wọ́n dìbò yàán- gẹ́gẹ́ bí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó ní ọdún 2019 lábẹ́ àsíá ẹgbẹ́ òṣèlú APC. Lẹ́yìn ti Gomina àná, Ìpínlẹ̀ Eko, Akinwunmi Ambode jakule ninu idibo abele egbe All Progressive Congress. [1] [2] [3] [4]
Quick Facts 15th Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó, Deputy ...
Babajide Olusola Sanwo-Olu | |
---|---|
Babajide Sanwo-Olu | |
15th Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó | |
In office 29 Oṣù Kàrún 2015 – seronja | |
Deputy | Femi Hamzat |
Asíwájú | Akinwunmi Ambode |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressives Congress |
Education | University of Lagos Lagos Business School John F. Kennedy School of Government London Business School |
Occupation | Banker, Politician |
Close