Baselios Cleemis
From Wikipedia, the free encyclopedia
Baselios Cleemis Thottunkal (Malayalam: ബസേലിയോസ് കർദ്ദിനാൾ ക്ലിമ്മീസ്) tàbí tí wọ́n bá fẹ́ gẹ́gẹ́ bí olórí ecclesiastical, Baselios Cleemis Cardinal Thottunkal[1][2][3][4][5] jẹ́ Major Archbishop ti Syro-Malankara Catholic Church. Pope Benedict XVI yànhán sí College of Cardinals tí Catholic Church ní Papal Basilica of Saint Peter ní Ọjọ́ kẹrìnlélógún Oṣù mọ́kànlá Ọdún 2012. Nígbà tí wọ́n yànhàn, òhun ló kéré jùlọ ní ẹgbẹ́ College of Cardinals. Ó jẹ́ olórí ecclesiastical Syro-Malankara Catholic Church àkọ́kọ́. Ní Ọjọ́ ọ̀kànlélọ́gbọ̀n Oṣù kínín Ọdún 2013, ó di ọmọ ẹgbẹ́ Congregation for the Oriental Churches àti ti Pontifical Council for Interreligious Dialogue. Ní Ọjọ́ kejìlá Oṣu kejìlá Ọdún 2013, wọ́n dìbò yànhàn gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ Kerala Catholic Bishops' Council. Ní Ọjọ́ kọkànlá Oṣù kejì Ọdún 2014, wọ́n dìbò yànhàn gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ Catholic Bishops' Conference of India.
His Eminence Baselios Cleemis | |
---|---|
Cardinal, Major Archbishop of Trivandrum | |
Church | Syro-Malankara Catholic Church |
Archdiocese | Trivandrum |
See | Trivandrum, India |
Enthroned | 5 March 2007 |
Predecessor | Cyril Baselios |
Ordination | 11 June 1986 |
Consecration | 15 August 2001 |
Created Cardinal | 24 November 2012 |
Rank | Cardinal-Priest |
Other |
|
Motto | To Unite in Love |
Personal details | |
Born | 15 Oṣù Kẹfà 1959 (1959-06-15) (ọmọ ọdún 64) Mukkoor, Thiruvalla, Kerala, India |
Parents | Mathew and Annamma Thottumkal |
Alma mater | Pontifical University of Saint Thomas Aquinas |