Billie Eilish
From Wikipedia, the free encyclopedia
Billie Eilish Pirate Baird O'Connell ( /ˈaɪlɪʃ/ EYE-lish;[2] tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù Kejìlá ọdún 2001) jẹ́ akọrin ọmọ orílè-èdè Amerika. Ó di gbajúgbajà ní ọdún 2015 nígbà tí ó ṣe àgbéjáde orin "Ocean Eyes", tí arákùnrin rẹ̀ Finneas O'Connell kọ sílẹ̀. Ní ọdún 2017, ó sàgbéjáde orin extended play (EP), Don't Smile at Me.
Quick Facts Ọjọ́ìbí, Iṣẹ́ ...
Billie Eilish | |||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Eilish ní ọdún 2023 | |||||||||
Ọjọ́ìbí | Billie Eilish Pirate Baird O'Connell 18 Oṣù Kejìlá 2001 (2001-12-18) (ọmọ ọdún 22) Los Angeles, California, U.S. | ||||||||
Iṣẹ́ |
| ||||||||
Ìgbà iṣẹ́ | 2015–present | ||||||||
Works |
| ||||||||
Parent(s) |
| ||||||||
Àwọn olùbátan | Finneas O'Connell (brother) Brian Baird (uncle) | ||||||||
Awards | Full list | ||||||||
Musical career | |||||||||
Irú orin |
| ||||||||
Instruments |
| ||||||||
Labels |
| ||||||||
Website | billieeilish.com | ||||||||
| |||||||||
Signature | |||||||||
Close