Carl Friedrich Gauss
From Wikipedia, the free encyclopedia
Johann Carl Friedrich Gauss (pípè /ˈɡaʊs/; listen (ìrànwọ́·ìkéde), Látìnì: Carolus Fridericus Gauss) (30 April 1777 – 23 February 1855) je ara Germany onimo-mathematiki ati onimosayensi ti o ko ipa to se koko ninu opo omo ijinle, bi iro nomba, statistiki, ituyewo mathematiki, Jeometria oniyato, geodesy, geophysics, electrostatics, itorawo ati iriran. Won pe ni Princeps mathematicorum[1] (Latini, fun "Arole awon Onimo-mathematiki" tabi "asiwaju awon onimo-mathematiki") ati "onimo-mathematiki olokikijulo lati atijo", Gauss ko ipa gidigidi ninu opo papa imo mathematiki ati sayensi.[2] He referred to mathematics as "the queen of sciences."[3]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Carl Friedrich Gauss | |
---|---|
Johann Carl Friedrich Gauss (1777–1855), painted by Christian Albrecht Jensen | |
Ìbí | (1777-04-30)30 Oṣù Kẹrin 1777 Braunschweig, Electorate of Brunswick-Lüneburg, Holy Roman Empire |
Aláìsí | 23 February 1855(1855-02-23) (ọmọ ọdún 77) Göttingen, Kingdom of Hanover |
Ibùgbé | Kingdom of Hanover |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | German |
Pápá | Mathematician and physicist |
Ilé-ẹ̀kọ́ | University of Göttingen |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of Helmstedt |
Doctoral advisor | Johann Friedrich Pfaff |
Other academic advisors | Johann Christian Martin Bartels |
Doctoral students | Friedrich Bessel Christoph Gudermann Christian Ludwig Gerling Richard Dedekind Johann Encke Johann Listing Bernhard Riemann Christian Peters Moritz Cantor |
Other notable students | August Ferdinand Möbius Julius Weisbach L. C. Schnürlein |
Ó gbajúmọ̀ fún | See full list |
Influenced | Sophie Germain |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Copley Medal (1838) |
Signature |